Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 26:58 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìdílé tí ó wà ninu ẹ̀yà Lefi nìwọ̀nyí: ìdílé Libini, ìdílé Heburoni, ìdílé Mahili, ìdílé Muṣi ati ìdílé Kora. Kohati ni baba Amramu.

Ka pipe ipin Nọmba 26

Wo Nọmba 26:58 ni o tọ