Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 26:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ aya Amramu ni Jokebedi, ọmọbinrin Lefi tí ìyá rẹ̀ bí fún Lefi ní Ijipti. Ó bí Aaroni ati Mose ati Miriamu, arabinrin wọn fún Amramu.

Ka pipe ipin Nọmba 26

Wo Nọmba 26:59 ni o tọ