Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní tiwa, a ti gbìyànjú níwọ̀n bí agbára wa ti mọ, a ti ra àwọn arakunrin wa tí wọ́n tà lẹ́rú fún àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn pada, ṣugbọn ẹ̀yin tún ń ta àwọn arakunrin yín, kí wọ́n baà lè tún tà wọ́n fún wa!” Wọ́n dákẹ́, wọn kò sì lè fọhùn.

Ka pipe ipin Nehemaya 5

Wo Nehemaya 5:8 ni o tọ