Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rò ó lọ́kàn mi, mo sì dá àwọn ọlọ́lá ati àwọn ìjòyè lẹ́bi. Mo sọ fún wọn pé, “Ẹ̀ ń ni àwọn arakunrin yín lára.”Mo bá pe ìpàdé ńlá lé wọn lórí, mo sọ fún wọn pé,

Ka pipe ipin Nehemaya 5

Wo Nehemaya 5:7 ni o tọ