Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá sọ pé, “Ohun tí ẹ̀ ń ṣe kò dára. Ǹjẹ́ kò yẹ kí ẹ máa fi ìbẹ̀rù rìn ní ọ̀nà Ọlọrun, kí àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jẹ́ ọ̀tá wa má baà máa kẹ́gàn wa?

Ka pipe ipin Nehemaya 5

Wo Nehemaya 5:9 ni o tọ