Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá gbadura pé, “Gbọ́, Ọlọrun wa, nítorí pé wọ́n kẹ́gàn wa. Yí ẹ̀gàn wọn pada lé wọn lórí, kí o sì fi wọ́n lé alágbèédá lọ́wọ́ ní ilẹ̀ tí wọ́n kó wọn lẹ́rú lọ.

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:4 ni o tọ