Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Má mójú fo àìdára wọn, má sì pa ẹ̀ṣẹ̀ wọn rẹ́ kúrò ninu àkọsílẹ̀ tí ó wà níwájú rẹ, nítorí pé wọ́n ti mú ọ bínú níwájú àwọn tí wọn ń mọ odi.”

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:5 ni o tọ