Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Tobaya ará Amoni náà sì fara mọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní, “Bẹ́ẹ̀ ni, bí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun orí ohun tí wọ́n mọ, tí wọn ń pè ní odi olókùúta, wíwó ni yóo wó o lulẹ̀!”

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:3 ni o tọ