Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Salu ati Amoku, Hilikaya, ati Jedaaya. Àwọn ni wọ́n jẹ́ olórí alufaa ati olórí àwọn arakunrin wọn ní ìgbà ayé Jeṣua.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:7 ni o tọ