Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi ni: Jeṣua, Binui ati Kadimieli; Ṣerebaya, Juda, ati Matanaya, tí òun pẹlu àwọn arakunrin rẹ̀ wà nídìí ètò àwọn orin ọpẹ́.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:8 ni o tọ