Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí kò bá ní agbára láti mú ọ̀dọ́ aguntan wá, ohun tí ó tún lè mú tọ OLUWA wá gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ ni àdàbà meji tabi ọmọ ẹyẹlé meji, ọ̀kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, ekeji fún ẹbọ sísun.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:7 ni o tọ