Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó kó wọn wá sọ́dọ̀ alufaa, kí alufaa sì fi ekinni rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀. Lílọ́ ni kí alufaa lọ́ ọ lọ́rùn, ṣugbọn kí ó má fà á lọ́rùn tu.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:8 ni o tọ