Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:6 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ó sì mú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ wá sọ́dọ̀ OLUWA fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá. Kí ó mú abo ọ̀dọ́ aguntan, tabi ti ewúrẹ́ wá fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, alufaa yóo sì ṣe ètùtù fún un nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:6 ni o tọ