Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tabi bí ó bá fara kan ohun aláìmọ́ kan lára eniyan, ohun yòówù kí ohun náà jẹ́, ó ti sọ ẹni náà di aláìmọ́, bí irú ohun bẹ́ẹ̀ bá pamọ́ fún un, ìgbà yòówù tí ó bá mọ̀, ó jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:3 ni o tọ