Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tabi bí ẹnikẹ́ni bá fi ẹnu ara rẹ̀ búra láìronú, kì báà jẹ́ láti ṣe ibi ni, tabi láti ṣe rere, irú ìbúra kíbùúra tí eniyan lè ṣe láìmọ̀, nígbà tí ó bá mọ̀, ó di ẹlẹ́bi.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:4 ni o tọ