Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan bá fẹ́ iyawo, tí ó sì tún fẹ́ ìyá iyawo náà pẹlu, ìwà burúkú ni; sísun ni kí wọ́n sun wọ́n níná, ati ọkunrin ati àwọn obinrin mejeeji, kí ìwà burúkú má baà wà láàrin yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:14 ni o tọ