Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọkunrin kan bá bá ọkunrin ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lòpọ̀ bí a ti ń bá obinrin lòpọ̀, àwọn mejeeji ti ṣe ohun ìríra; pípa ni kí wọ́n pa wọ́n, ẹ̀jẹ̀ wọn yóo wà lórí ara wọn.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:13 ni o tọ