Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:37 BIBELI MIMỌ (BM)

sibẹ, tí wọ́n bá ranti, tí wọ́n sì ronupiwada ní ilẹ̀ tí wọ́n kó wọn lẹ́rú lọ, tí wọ́n bá bẹ̀bẹ̀ tí wọ́n sọ pé, ‘àwọn ti ṣẹ̀, àwọn ti hu ìwà tí kò tọ́, àwọn sì ti ṣe burúkú,’

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:37 ni o tọ