Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:38 BIBELI MIMỌ (BM)

tí wọ́n bá ronupiwada tọkàntọkàn ninu ìgbèkùn níbi tí a kó wọn lẹ́rú lọ, tí wọ́n gbadura sí ìhà ilẹ̀ tí o fún àwọn baba wọn, ati sí ìlú tí o ti yàn, ati sí ilé tí mo kọ́ fún ìjọ́sìn ní orúkọ rẹ,

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:38 ni o tọ