Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:36 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí wọ́n bá ṣẹ̀ ọ́ (nítorí pé kò sí ẹni tí kì í ṣẹ̀), tí inú bá bí ọ sí wọn, tí o sì mú kí àwọn ọ̀tá wọn ṣẹgun wọn, tí wọ́n sì kó wọn lẹ́rú lọ sí ọ̀nà jíjìn tabi nítòsí,

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:36 ni o tọ