Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 35:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ìsìn Àjọ Ìrékọjá ati ti ẹbọ sísun lórí pẹpẹ OLUWA ní ọjọ́ náà gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Josaya ọba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:16 ni o tọ