Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 35:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn akọrin tí wọ́n jẹ́ ọmọ Asafu dúró ní ipò wọn gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Dafidi. Bẹ́ẹ̀ náà ni Asafu, Hemani, ati Jedutuni, aríran ọba. Àwọn aṣọ́nà tẹmpili kò kúrò ní ààyè wọn, nítorí pé àwọn ọmọ Lefi ti tọ́jú ẹbọ ìrékọjá tiwọn fún wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:15 ni o tọ