Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 31:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní kété tí àṣẹ yìí tàn káàkiri, wọ́n mú ọpọlọpọ àkọ́so ọkà, ati ọtí ati òróró ati oyin, ati àwọn nǹkan irè oko mìíràn wá. Wọ́n tún san ìdámẹ́wàá gbogbo nǹkan tí wọ́n ní.

Ka pipe ipin Kronika Keji 31

Wo Kronika Keji 31:5 ni o tọ