Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 31:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ati ti Juda tí wọn ń gbé àwọn ìlú Juda náà san ìdámẹ́wàá mààlúù ati aguntan, ati ti àwọn ohun mímọ́ tí wọ́n ti yà sọ́tọ̀ fún OLUWA Ọlọrun wọn, wọ́n kó wọn jọ bí òkítì.

Ka pipe ipin Kronika Keji 31

Wo Kronika Keji 31:6 ni o tọ