Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ẹnikẹ́ni wọnú ilé OLUWA, àfi àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n wà lẹ́nu iṣẹ́. Àwọn lè wọlé nítorí pé wọ́n mọ́. Ṣugbọn àwọn eniyan tí ó kù gbọdọ̀ pa àṣẹ OLUWA mọ́.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:6 ni o tọ