Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi yóo yí ọba ká láti ṣọ́ ọ, olukuluku yóo mú ohun ìjà rẹ̀ lọ́wọ́, wọ́n gbọdọ̀ wà pẹlu ọba níbikíbi tí ó bá ń lọ. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ wọnú ilé Ọlọrun, pípa ni kí ẹ pa á.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:7 ni o tọ