Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ìdámẹ́ta yóo wà ní ààfin ọba, ìdámẹ́ta tó kù yóo máa ṣọ́ Ẹnubodè Ìpìlẹ̀; gbogbo àwọn eniyan yóo sì péjọ sí gbọ̀ngàn ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:5 ni o tọ