Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 13:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ilẹ̀ wọn ni ìdajì Gileadi wà ati Aṣitarotu ati Edirei, àwọn ìlú ńláńlá ilẹ̀ ìjọba Ogu, ọba Baṣani; Mose pín wọn fún àwọn ìdajì ìdílé Makiri, ọmọ Manase, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 13

Wo Joṣua 13:31 ni o tọ