Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ tiwọn bẹ̀rẹ̀ láti Mahanaimu, títí dé gbogbo ilẹ̀ Baṣani, gbogbo ilẹ̀ ìjọba Ogu, ọba Baṣani, ati gbogbo àwọn ìlú Jairi tí ó wà ní Baṣani, gbogbo ìlú wọn jẹ́ ọgọta.

Ka pipe ipin Joṣua 13

Wo Joṣua 13:30 ni o tọ