Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 32:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo farabalẹ̀ fun yín,ṣugbọn kò sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí ó lè ko Jobu lójú,kí ó sì fi àṣìṣe rẹ̀ hàn án,tabi kí ó fún un lésì àwọn àwíjàre rẹ̀.

Ka pipe ipin Jobu 32

Wo Jobu 32:12 ni o tọ