Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibinu ìwọ OLUWA mú kí inú mi máa ru,ara mi kò sì gbà á mọ́.”OLUWA bá sọ fún mi pé,“Tú ibinu mi dà sórí àwọn ọmọde ní ìta gbangba,ati àwọn ọdọmọkunrin níbi tí wọ́n péjọ sí.Ogun yóo kó wọn, tọkọtaya,àtàwọn àgbàlagbà àtàwọn arúgbó kùjọ́kùjọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:11 ni o tọ