Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní, “Ta ni kí n bá sọ̀rọ̀, tí yóo gbọ́?Ta ni kí n kìlọ̀ fún tí yóo gbà?Etí wọn ti di, wọn kò lè gbọ́ràn mọ́.Ọ̀rọ̀ OLUWA ń rùn létí wọn,wọn kò fẹ́ gbọ́ mọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:10 ni o tọ