Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn ti fá irun orí ati irùngbọ̀n wọn; wọ́n ti fi abẹ ya gbogbo ọwọ́ wọn, wọ́n sì lọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ mọ́ ìbàdí.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:37 ni o tọ