Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:36 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà ni mo ṣe ń dárò Moabu ati àwọn ará Kiri Heresi bí ẹni fi fèrè kọ orin arò nítorí pé gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n kó jọ ti ṣègbé.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:36 ni o tọ