Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 47:4 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ọjọ́ tí ń bọ̀, tí yóo jẹ́ ọjọ́ ìparun gbogbo àwọn ará Filistia,ọjọ́ tí a óo run gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ tí ó kù fún Tire ati Sidoni.Nítorí pé OLUWA yóo pa àwọn ará Filistia run,àwọn tí wọ́n kù ní etí òkun ní Kafitori.

Ka pipe ipin Jeremaya 47

Wo Jeremaya 47:4 ni o tọ