Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 47:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin bá ń dún,tí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ bá ń sáré,tí ẹsẹ̀ àwọn kẹ̀kẹ́ ogun sì ń pariwo,Àwọn baba kò ní lè wo àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn pé kí àwọn fà wọ́n,nítorí pé ọwọ́ wọn yóo rọ;

Ka pipe ipin Jeremaya 47

Wo Jeremaya 47:3 ni o tọ