Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣebí OLUWA ranti turari tí ẹ̀yin ati àwọn baba yín, ati àwọn ọba yín, ati àwọn ìjòyè yín, ati gbogbo àwọn eniyan ilẹ̀ náà sun ninu àwọn ìlú Juda ati ní ìgboro Jerusalẹmu, ṣebí OLUWA ranti.

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:21 ni o tọ