Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA kò lè farada ìwà burúkú tí ẹ̀ ń hù, ati àwọn nǹkan ìríra tí ẹ̀ ń ṣe, nítorí náà, ni ilẹ̀ yín ṣe di ahoro ati aṣálẹ̀, ati ilẹ̀ tí a fi ń gégùn-ún, tí kò ní olùgbé, títí di òní.

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:22 ni o tọ