Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn láti ìgbà tí a ti dáwọ́ ati máa sun turari sí ọbabinrin ojú ọ̀run dúró, tí a kò sì máa ta ohun mímu sílẹ̀ mọ́, ni a kò ti ní nǹkankan mọ́, tí ogun ati ìyàn sì fẹ́ẹ̀ pa wá tán.”

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:18 ni o tọ