Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn obinrin bá tún dáhùn pé, “Nígbà tí à ń sun turari sí ọbabinrin ojú ọ̀run, tí a sì ń rú ẹbọ ohun mímu sí i, ṣé àwọn ọkọ wa ni kò mọ̀ pé à ń ṣe àkàrà dídùn, tí à ń ṣe bí ère rẹ̀ fún un ni, ati pé à ń ta ohun mímu sílẹ̀ fún un?”

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:19 ni o tọ