Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 38:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA ní, ẹni tí ó bá dúró ní ìlú Jerusalẹmu yóo kú ikú idà, ìyàn ati àjàkálẹ̀ àrùn; ṣugbọn àwọn tí wọn bá jáde tọ àwọn ará Kalidea lọ yóo yè. Ó ní ọ̀rọ̀ wọn yóo dàbí ẹni tí ó ja àjàbọ́, ṣugbọn yóo wà láàyè.

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:2 ni o tọ