Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 38:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ṣefataya, ọmọ Matani, ati Gedalaya, ọmọ Paṣuri, ati Jukali, ọmọ Ṣelemaya, ati Paṣuri ọmọ Malikaya gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ fún gbogbo àwọn eniyan pé,

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:1 ni o tọ