Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 38:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya bá wí fún Sedekaya pé, “OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, bí o bá jọ̀wọ́ ara rẹ fún àwọn ìjòyè ọba Babiloni, wọn ó dá ẹ̀mí rẹ sí, wọn kò sì ní dáná sun ìlú yìí, ìwọ ati àwọn ará ilé rẹ yóo sì yè.

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:17 ni o tọ