Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 38:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Sedekaya ọba bá búra fún Jeremaya ní ìkọ̀kọ̀ pé, “Mo fi OLUWA alààyè ẹni tí ó dá ẹ̀mí wa búra, pé n kò ní pa ọ́, n kò sì ní fi ọ́ lé àwọn tí wọn ń wá ọ̀nà láti pa ọ́ lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:16 ni o tọ