Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí pé, “Nítorí pé àwọn eniyan mi ṣe nǹkan burúkú meji:wọ́n ti kọ èmi orísun omi ìyè sílẹ̀,wọ́n ṣe kànga fún ara wọn;kànga tí ó ti là, tí kò lè gba omi dúró.

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:13 ni o tọ