Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣé ẹrú ni Israẹli ni,àbí ọmọ ẹrú tí ẹrú bí sinu ilé?Báwo ló ṣe wá di ìjẹ fún àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:14 ni o tọ