Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Bí o bá àwọn tí ń fi ẹsẹ̀ sáré sáré, tí ó bá rẹ̀ ọ́,báwo ni o ṣe lè bá ẹṣin sáré?Bí o bá sì ń ṣubú ní ilẹ̀ tí ó tẹ́jú,báwo ni o óo ti ṣe nígbà tí o bá dé aṣálẹ̀ Jọdani?

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:5 ni o tọ