Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé àwọn arakunrin rẹ pàápàáati àwọn ará ilé baba rẹti hu ìwà ọ̀dàlẹ̀ sí ọ;àwọn gan-an ni wọ́n ń ṣe èké rẹ:Má gbẹ́kẹ̀lé wọn,bí wọ́n bá tilẹ̀ ń sọ̀rọ̀ rere sí ọ.”

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:6 ni o tọ