Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti pẹ́ tó, tí ilẹ̀ náà yóo máa ṣọ̀fọ̀,tí koríko oko yóo rọ?Nítorí iṣẹ́ burúkú àwọn tí wọn ń gbé inú rẹ̀,àwọn ẹranko ati àwọn ẹyẹ ṣègbé,nítorí àwọn eniyan ń wí pé,“Kò ní rí ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí wa.”

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:4 ni o tọ