Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 50:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Kenaani tí wọn ń gbé ibẹ̀ rí i bí wọ́n ti ń ṣọ̀fọ̀ ní ibi ìpakà náà, wọ́n wí pé, “Òkú yìí mà kúkú dun àwọn ará Ijipti o!” Nítorí náà, wọ́n sọ ibẹ̀ ní Abeli Misiraimu, ó wà ní apá ìlà oòrùn odò Jọdani.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:11 ni o tọ